I no fit lie you, wetin my eye don see, ó pọ̀ gan (hm-hm) So many good wey man don do, but na bad dem go talk (hm-hm) Even Jesus Christ, the Lord, dem nail am for cross (hm-hm) You no fit please everybody, ọmọ, o mọ p'ẹnu l'ẹbọ o (It's not personal, rárá o) Personal, rárá o, rárá o No give me yawa o (yawa o), no give me yawa o, yawa o Ọmọ arayé kala o, tí o bá wá sí owó, wọ́n máa japa o Don't take it personal (ahn), owọ́ epo lọn bá'ni lá (Hmm) Mo ṣ'oríre méje-méje (hmm) Orí mi, kó ma kọ́ blessing (hmm) Credit alert (hmm) Gratitude ṣa ni Mo ṣ'oríre méje-méje (mọ ṣ'ori re) Orí mi, kó má kọ́ blessing (orí mi) Credit alert Gratitude (ṣa ni) It's not personal, rárá o (rárá o) Personal, rárá o, rárá o No give me yawa o (yawa o) no give me yawa o, yawa o Ọmọ arayé kala o (kala), tí o bá sí owó wọ́n má japa o Don't take it personal, owọ́ epo l'ọ́n bá'ni lá (Hmm) Mo ṣ'oríre méje-méje (orírẹ) Orí mi, kó máa kó blessing (orí mi) Credit alert Gratitude ṣa ni Mo ṣ'oríre méje-méje (mo ṣ'orirẹ) Orí mi, kó má kó blessing (orí mi) Credit alert Gratitude (ṣa ni)